Jẹ́nẹ́sísì 46:15 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 15 Àwọn ni ọmọkùnrin tí Líà bí fún Jékọ́bù ní Padani-árámù, pẹ̀lú Dínà+ ọmọbìnrin rẹ̀. Gbogbo àwọn ọmọkùnrin àti ọmọbìnrin rẹ̀* jẹ́ mẹ́tàlélọ́gbọ̀n (33).
15 Àwọn ni ọmọkùnrin tí Líà bí fún Jékọ́bù ní Padani-árámù, pẹ̀lú Dínà+ ọmọbìnrin rẹ̀. Gbogbo àwọn ọmọkùnrin àti ọmọbìnrin rẹ̀* jẹ́ mẹ́tàlélọ́gbọ̀n (33).