Jẹ́nẹ́sísì 34:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Nígbà tí Ṣékémù, ọmọ Hámórì, ọmọ Hífì,+ tó jẹ́ ìjòyè ilẹ̀ náà rí i, ó mú un, ó sì bá a sùn, ó fipá bá a lò pọ̀.
2 Nígbà tí Ṣékémù, ọmọ Hámórì, ọmọ Hífì,+ tó jẹ́ ìjòyè ilẹ̀ náà rí i, ó mú un, ó sì bá a sùn, ó fipá bá a lò pọ̀.