Jẹ́nẹ́sísì 24:59 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 59 Torí náà, wọ́n jẹ́ kí Rèbékà+ arábìnrin wọn àti olùtọ́jú*+ rẹ̀ tẹ̀ lé ìránṣẹ́ Ábúráhámù àti àwọn ọkùnrin tí wọ́n jọ wá.
59 Torí náà, wọ́n jẹ́ kí Rèbékà+ arábìnrin wọn àti olùtọ́jú*+ rẹ̀ tẹ̀ lé ìránṣẹ́ Ábúráhámù àti àwọn ọkùnrin tí wọ́n jọ wá.