Jẹ́nẹ́sísì 28:19 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 19 Ó wá pe orúkọ ibẹ̀ ní Bẹ́tẹ́lì,* àmọ́ Lúsì+ ni ìlú náà ń jẹ́ tẹ́lẹ̀.