Mátíù 23:35 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 35 kí ẹ lè jẹ̀bi ẹ̀jẹ̀ gbogbo àwọn olódodo tí wọ́n ta sílẹ̀ ní ayé, látorí ẹ̀jẹ̀ Ébẹ́lì+ olódodo dórí ẹ̀jẹ̀ Sekaráyà ọmọ Barakáyà, ẹni tí ẹ pa láàárín ibi mímọ́ àti pẹpẹ.+
35 kí ẹ lè jẹ̀bi ẹ̀jẹ̀ gbogbo àwọn olódodo tí wọ́n ta sílẹ̀ ní ayé, látorí ẹ̀jẹ̀ Ébẹ́lì+ olódodo dórí ẹ̀jẹ̀ Sekaráyà ọmọ Barakáyà, ẹni tí ẹ pa láàárín ibi mímọ́ àti pẹpẹ.+