-
Jẹ́nẹ́sísì 36:18Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
18 Àwọn ọmọ Oholibámà ìyàwó Ísọ̀ sì nìyí: Séríkí Jéúṣì, Séríkí Jálámù àti Séríkí Kórà. Àwọn ni séríkí nínú àwọn ọmọ Oholibámà ọmọ Ánáhì, ìyàwó Ísọ̀.
-