-
Jẹ́nẹ́sísì 36:17Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
17 Àwọn ọmọkùnrin Réúẹ́lì ọmọ Ísọ̀ nìyí: Séríkí Náhátì, Séríkí Síírà, Séríkí Ṣámà àti Séríkí Mísà. Àwọn ni séríkí nínú àwọn ọmọ Réúẹ́lì ní ilẹ̀ Édómù.+ Àwọn ni ọmọ Básémátì ìyàwó Ísọ̀.
-