Jẹ́nẹ́sísì 25:30 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 30 Torí náà Ísọ̀ sọ fún Jékọ́bù pé: “Jọ̀ọ́, sáré fún mi lára* ọbẹ̀ pupa tí ò ń sè yẹn,* torí ó ti rẹ̀ mí!”* Ìdí nìyẹn tí orúkọ rẹ̀ fi ń jẹ́ Édómù.*+ Jẹ́nẹ́sísì 32:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Nígbà náà, Jékọ́bù ní kí àwọn ìránṣẹ́ rẹ̀ kọ́kọ́ lọ sọ́dọ̀ Ísọ̀ ẹ̀gbọ́n rẹ̀ ní ilẹ̀ Séírì,+ ní agbègbè* Édómù,+
30 Torí náà Ísọ̀ sọ fún Jékọ́bù pé: “Jọ̀ọ́, sáré fún mi lára* ọbẹ̀ pupa tí ò ń sè yẹn,* torí ó ti rẹ̀ mí!”* Ìdí nìyẹn tí orúkọ rẹ̀ fi ń jẹ́ Édómù.*+
3 Nígbà náà, Jékọ́bù ní kí àwọn ìránṣẹ́ rẹ̀ kọ́kọ́ lọ sọ́dọ̀ Ísọ̀ ẹ̀gbọ́n rẹ̀ ní ilẹ̀ Séírì,+ ní agbègbè* Édómù,+