51 Lẹ́yìn náà, Hádádì kú.
Àwọn séríkí Édómù ni Séríkí Tímínà, Séríkí Álíífà, Séríkí Jététì,+ 52 Séríkí Oholibámà, Séríkí Élà, Séríkí Pínónì, 53 Séríkí Kénásì, Séríkí Témánì, Séríkí Míbúsárì, 54 Séríkí Mágídíélì, Séríkí Írámù. Àwọn yìí ni séríkí Édómù.