Jẹ́nẹ́sísì 25:30 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 30 Torí náà Ísọ̀ sọ fún Jékọ́bù pé: “Jọ̀ọ́, sáré fún mi lára* ọbẹ̀ pupa tí ò ń sè yẹn,* torí ó ti rẹ̀ mí!”* Ìdí nìyẹn tí orúkọ rẹ̀ fi ń jẹ́ Édómù.*+ Jẹ́nẹ́sísì 36:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Ísọ̀ wá ń gbé ní agbègbè olókè Séírì.+ Ísọ̀ ni Édómù.+
30 Torí náà Ísọ̀ sọ fún Jékọ́bù pé: “Jọ̀ọ́, sáré fún mi lára* ọbẹ̀ pupa tí ò ń sè yẹn,* torí ó ti rẹ̀ mí!”* Ìdí nìyẹn tí orúkọ rẹ̀ fi ń jẹ́ Édómù.*+