-
Jẹ́nẹ́sísì 47:3Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
3 Fáráò bi àwọn arákùnrin Jósẹ́fù pé: “Iṣẹ́ wo lẹ̀ ń ṣe?” Wọ́n fèsì pé: “Olùṣọ́ àgùntàn ni àwa ìránṣẹ́ rẹ, àwa àti àwọn baba ńlá+ wa.”
-