Jẹ́nẹ́sísì 40:2, 3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Fáráò wá bínú sí àwọn òṣìṣẹ́ rẹ̀ méjèèjì, ìyẹn olórí agbọ́tí àti olórí alásè,+ 3 ó sì jù wọ́n sí ẹ̀wọ̀n ní ilé olórí ẹ̀ṣọ́,+ níbi tí Jósẹ́fù ti ń ṣẹ̀wọ̀n.+
2 Fáráò wá bínú sí àwọn òṣìṣẹ́ rẹ̀ méjèèjì, ìyẹn olórí agbọ́tí àti olórí alásè,+ 3 ó sì jù wọ́n sí ẹ̀wọ̀n ní ilé olórí ẹ̀ṣọ́,+ níbi tí Jósẹ́fù ti ń ṣẹ̀wọ̀n.+