-
Rúùtù 4:6Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
6 Olùtúnrà náà fèsì pé: “Mi ò lè tún un rà, torí kí n má bàa run ogún tèmi. Mo yọ̀ǹda fún ọ láti tún un rà, torí mi ò ní lè tún un rà.”
-