-
Diutarónómì 25:7Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
7 “Àmọ́ tí ọkùnrin náà kò bá fẹ́ ṣú ìyàwó arákùnrin rẹ̀ lópó, kí ìyàwó arákùnrin rẹ̀ tó kú náà lọ bá àwọn àgbààgbà ní ẹnubodè ìlú, kó sì sọ fún wọn pé, ‘Arákùnrin ọkọ mi kò fẹ́ kí orúkọ arákùnrin rẹ̀ ṣì máa wà ní Ísírẹ́lì. Kò gbà láti ṣú mi lópó.’
-