Jẹ́nẹ́sísì 4:15 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 15 Jèhófà wá sọ fún un pé: “Kí ìyẹn má bàa ṣẹlẹ̀, ẹnikẹ́ni tó bá pa Kéènì yóò jìyà ìlọ́po méje.” Jèhófà wá ṣe àmì kan* fún Kéènì kí ẹnikẹ́ni tó bá rí i má bàa pa á.
15 Jèhófà wá sọ fún un pé: “Kí ìyẹn má bàa ṣẹlẹ̀, ẹnikẹ́ni tó bá pa Kéènì yóò jìyà ìlọ́po méje.” Jèhófà wá ṣe àmì kan* fún Kéènì kí ẹnikẹ́ni tó bá rí i má bàa pa á.