-
Jẹ́nẹ́sísì 38:11Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
11 Júdà sọ fún Támárì ìyàwó ọmọ rẹ̀ pé: “Lọ máa ṣe opó ní ilé bàbá rẹ títí Ṣélà ọmọ mi yóò fi dàgbà,” torí ó sọ lọ́kàn ara rẹ̀ pé: “Òun náà lè kú bíi ti àwọn ẹ̀gbọ́n+ rẹ̀.” Támárì wá lọ ń gbé ní ilé bàbá rẹ̀.
-