-
Ẹ́kísódù 3:16Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
16 Wá lọ, kí o kó àwọn àgbààgbà Ísírẹ́lì jọ, kí o sì sọ fún wọn pé, ‘Jèhófà Ọlọ́run àwọn baba ńlá yín ti fara hàn mí, Ọlọ́run Ábúráhámù, Ísákì àti Jékọ́bù, ó sì sọ pé: “Mo ti kíyè sí yín,+ mo sì ti rí ohun tí wọ́n ń ṣe sí yín ní Íjíbítì.
-
-
Ẹ́kísódù 24:1Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
24 Ó wá sọ fún Mósè pé: “Kí ìwọ àti Áárónì gòkè lọ sọ́dọ̀ Jèhófà, pẹ̀lú Nádábù àti Ábíhù+ àti àádọ́rin (70) nínú àwọn àgbààgbà Ísírẹ́lì, kí ẹ sì tẹrí ba láti òkèèrè.
-