-
Ẹ́kísódù 4:3Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
3 Ọlọ́run sọ pé: “Jù ú sílẹ̀.” Ó jù ú sílẹ̀, ló bá di ejò;+ Mósè sì sá fún un.
-
-
Ẹ́kísódù 4:6Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
6 Jèhófà tún sọ fún un pé: “Jọ̀ọ́, ki ọwọ́ rẹ bọ inú aṣọ rẹ lápá òkè.” Ó wá ki ọwọ́ bọ inú aṣọ rẹ̀. Nígbà tó yọ ọ́ jáde, ẹ̀tẹ̀ ti bò ó lọ́wọ́, ó sì funfun bíi yìnyín!+
-
-
Ẹ́kísódù 4:9Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
9 Síbẹ̀, tí wọn ò bá gba àmì méjèèjì yìí gbọ́, tí wọn ò sì fetí sí ọ, kí o bu omi díẹ̀ látinú odò Náílì, kí o sì dà á sórí ilẹ̀, omi tí o bù nínú odò Náílì yóò sì di ẹ̀jẹ̀ lórí ilẹ̀.”+
-