Ẹ́kísódù 28:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Kí o bá gbogbo àwọn tó mọṣẹ́* sọ̀rọ̀, àwọn tí mo ti fi ẹ̀mí ọgbọ́n kún inú wọn,+ kí wọ́n lè ṣe aṣọ Áárónì láti sọ ọ́ di mímọ́, kó lè di àlùfáà mi. Ẹ́kísódù 35:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 “‘Kí gbogbo àwọn tó mọṣẹ́*+ láàárín yín wá ṣe gbogbo ohun tí Jèhófà pa láṣẹ,
3 Kí o bá gbogbo àwọn tó mọṣẹ́* sọ̀rọ̀, àwọn tí mo ti fi ẹ̀mí ọgbọ́n kún inú wọn,+ kí wọ́n lè ṣe aṣọ Áárónì láti sọ ọ́ di mímọ́, kó lè di àlùfáà mi.