Ẹ́kísódù 25:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Kí ẹ ṣe àgọ́ ìjọsìn àti gbogbo ohun tó máa wà níbẹ̀, kó rí bí ohun* tí màá fi hàn ọ́ gẹ́lẹ́.+ Ẹ́kísódù 39:32 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 32 Wọ́n wá parí gbogbo iṣẹ́ àgọ́ ìjọsìn, àgọ́ ìpàdé náà, àwọn ọmọ Ísírẹ́lì sì ṣe gbogbo ohun tí Jèhófà pa láṣẹ fún Mósè.+ Wọ́n ṣe bẹ́ẹ̀ gẹ́lẹ́. Hébérù 9:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Àgọ́ yìí jẹ́ àpèjúwe fún àkókò yìí,+ a sì ń fi àwọn ọrẹ àti ẹbọ rúbọ ní ìbámu pẹ̀lú ètò yìí.+ Àmọ́ àwọn yìí ò lè mú kí ẹni tó ń ṣe iṣẹ́ ìsìn mímọ́ ní ẹ̀rí ọkàn tó mọ́ pátápátá.+
32 Wọ́n wá parí gbogbo iṣẹ́ àgọ́ ìjọsìn, àgọ́ ìpàdé náà, àwọn ọmọ Ísírẹ́lì sì ṣe gbogbo ohun tí Jèhófà pa láṣẹ fún Mósè.+ Wọ́n ṣe bẹ́ẹ̀ gẹ́lẹ́.
9 Àgọ́ yìí jẹ́ àpèjúwe fún àkókò yìí,+ a sì ń fi àwọn ọrẹ àti ẹbọ rúbọ ní ìbámu pẹ̀lú ètò yìí.+ Àmọ́ àwọn yìí ò lè mú kí ẹni tó ń ṣe iṣẹ́ ìsìn mímọ́ ní ẹ̀rí ọkàn tó mọ́ pátápátá.+