Jẹ́nẹ́sísì 50:25 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 25 Jósẹ́fù wá mú kí àwọn ọmọ Ísírẹ́lì búra, ó ní: “Ó dájú pé Ọlọ́run ò ní gbàgbé yín. Kí ẹ kó egungun mi kúrò níbí.”+
25 Jósẹ́fù wá mú kí àwọn ọmọ Ísírẹ́lì búra, ó ní: “Ó dájú pé Ọlọ́run ò ní gbàgbé yín. Kí ẹ kó egungun mi kúrò níbí.”+