Ẹ́kísódù 40:20 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 20 Lẹ́yìn náà, ó mú Ẹ̀rí,+ ó sì fi sínú Àpótí náà.+ Ó ki àwọn ọ̀pá+ sí ẹ̀gbẹ́ Àpótí náà, ó sì fi ìbòrí+ bo Àpótí náà.+
20 Lẹ́yìn náà, ó mú Ẹ̀rí,+ ó sì fi sínú Àpótí náà.+ Ó ki àwọn ọ̀pá+ sí ẹ̀gbẹ́ Àpótí náà, ó sì fi ìbòrí+ bo Àpótí náà.+