Hébérù 9:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 àwọn kérúbù ológo tí wọ́n ṣíji bo ìbòrí ìpẹ̀tù*+ sì wà lórí rẹ̀. Àmọ́ àkókò kọ́ nìyí láti máa sọ kúlẹ̀kúlẹ̀ àwọn nǹkan yìí.
5 àwọn kérúbù ológo tí wọ́n ṣíji bo ìbòrí ìpẹ̀tù*+ sì wà lórí rẹ̀. Àmọ́ àkókò kọ́ nìyí láti máa sọ kúlẹ̀kúlẹ̀ àwọn nǹkan yìí.