-
Ẹ́kísódù 27:17Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
17 Fàdákà ni kí o fi ṣe gbogbo òpó tó yí àgbàlá náà ká àti àwọn ohun tí wọ́n fi ń de nǹkan pọ̀ àti àwọn ìkọ́, àmọ́ bàbà ni kí o fi ṣe ìtẹ́lẹ̀ oníhò wọn.+
-