-
Nọ́ńbà 4:46, 47Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
46 Mósè àti Áárónì àti àwọn ìjòyè Ísírẹ́lì forúkọ gbogbo àwọn ọmọ Léfì yìí sílẹ̀ ní ìdílé-ìdílé àti agbo ilé bàbá wọn; 47 wọ́n jẹ́ ẹni ọgbọ̀n (30) ọdún sí àádọ́ta (50) ọdún, gbogbo wọn ni a yàn láti máa ṣiṣẹ́, kí wọ́n sì máa gbé àwọn ẹrù tó jẹ mọ́ àgọ́ ìpàdé.+
-