Ẹ́kísódù 6:23 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 23 Áárónì wá fi Élíṣébà, ọmọ Ámínádábù, arábìnrin Náṣónì+ ṣe aya. Ó bí Nádábù, Ábíhù, Élíásárì àti Ítámárì+ fún un. Nọ́ńbà 4:28 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 28 Èyí ni iṣẹ́ tí ìdílé àwọn ọmọ Gẹ́ṣónì á máa ṣe nínú àgọ́ ìpàdé,+ Ítámárì+ ọmọ àlùfáà Áárónì ni yóò sì máa darí iṣẹ́ wọn. 1 Kíróníkà 6:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Àwọn ọmọ* Ámúrámù+ ni Áárónì,+ Mósè+ àti Míríámù.+ Àwọn ọmọ Áárónì sì ni Nádábù, Ábíhù,+ Élíásárì+ àti Ítámárì.+
23 Áárónì wá fi Élíṣébà, ọmọ Ámínádábù, arábìnrin Náṣónì+ ṣe aya. Ó bí Nádábù, Ábíhù, Élíásárì àti Ítámárì+ fún un.
28 Èyí ni iṣẹ́ tí ìdílé àwọn ọmọ Gẹ́ṣónì á máa ṣe nínú àgọ́ ìpàdé,+ Ítámárì+ ọmọ àlùfáà Áárónì ni yóò sì máa darí iṣẹ́ wọn.
3 Àwọn ọmọ* Ámúrámù+ ni Áárónì,+ Mósè+ àti Míríámù.+ Àwọn ọmọ Áárónì sì ni Nádábù, Ábíhù,+ Élíásárì+ àti Ítámárì.+