Ẹ́kísódù 35:22 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 22 Wọ́n ń wá ṣáá, lọ́kùnrin àti lóbìnrin, kálukú ń wá láti ṣe ọrẹ látọkàn wá, wọ́n mú àwọn ohun ọ̀ṣọ́ tí wọ́n ń so mọ́ aṣọ wá, pẹ̀lú yẹtí, òrùka àti àwọn ohun ọ̀ṣọ́ míì, pẹ̀lú onírúurú ohun èlò wúrà. Gbogbo wọn mú ọrẹ* wúrà wá fún Jèhófà.+
22 Wọ́n ń wá ṣáá, lọ́kùnrin àti lóbìnrin, kálukú ń wá láti ṣe ọrẹ látọkàn wá, wọ́n mú àwọn ohun ọ̀ṣọ́ tí wọ́n ń so mọ́ aṣọ wá, pẹ̀lú yẹtí, òrùka àti àwọn ohun ọ̀ṣọ́ míì, pẹ̀lú onírúurú ohun èlò wúrà. Gbogbo wọn mú ọrẹ* wúrà wá fún Jèhófà.+