-
Ẹ́kísódù 35:23Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
23 Gbogbo àwọn tó ní fọ́nrán òwú aláwọ̀ búlúù, òwú aláwọ̀ pọ́pù àti òwú aláwọ̀ rírẹ̀dòdò sì mú wọn wá, pẹ̀lú aṣọ ọ̀gbọ̀ tó dáa, irun ewúrẹ́, awọ àgbò tí wọ́n pa láró pupa àti awọ séálì.
-