-
Ẹ́kísódù 28:12Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
12 Kí o fi òkúta méjèèjì sórí àwọn aṣọ èjìká éfódì náà, kó lè jẹ́ òkúta ìrántí fún àwọn ọmọ Ísírẹ́lì,+ kí orúkọ wọn sì máa wà ní èjìká Áárónì méjèèjì, kó lè jẹ́ ohun ìrántí tó bá wá síwájú Jèhófà.
-