Ẹ́kísódù 28:42 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 42 Kí o tún fi aṣọ ọ̀gbọ̀ ṣe ṣòkòtò péńpé* fún wọn kó lè bo ìhòòhò wọn.+ Kó gùn láti ìbàdí dé itan.