ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Ẹ́kísódù 29:36, 37
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 36 Kí o máa fi akọ màlúù tó wà fún ẹbọ ẹ̀ṣẹ̀ rúbọ lójoojúmọ́ láti fi ṣe ètùtù, kí o sì ṣe ètùtù fún pẹpẹ náà láti wẹ ẹ̀ṣẹ̀ kúrò lára rẹ̀, kí o sì fòróró yàn án láti sọ ọ́ di mímọ́.+ 37 Ọjọ́ méje ni kí o fi ṣe ètùtù fún pẹpẹ náà, kí o sì sọ ọ́ di mímọ́ kó lè di pẹpẹ mímọ́ jù lọ.+ Ẹnikẹ́ni tó bá fara kan pẹpẹ náà ti gbọ́dọ̀ jẹ́ mímọ́.

  • Léfítíkù 8:11
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 11 Lẹ́yìn náà, ó wọ́n lára rẹ̀ sórí pẹpẹ lẹ́ẹ̀méje, ó sì fòróró yan pẹpẹ àti gbogbo ohun èlò rẹ̀ àti bàsíà àti ẹsẹ̀ rẹ̀ láti yà wọ́n sí mímọ́.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́