-
Ẹ́kísódù 5:7, 8Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
7 “Ẹ ò gbọ́dọ̀ fún àwọn èèyàn náà ní pòròpórò mọ́ láti fi ṣe bíríkì.+ Ẹ jẹ́ kí wọ́n lọ máa wá a fúnra wọn. 8 Àmọ́ ẹ gbọ́dọ̀ rí i pé iye bíríkì tí wọ́n ń ṣe tẹ́lẹ̀ náà ni wọ́n ṣì ń ṣe. Ẹ ò gbọ́dọ̀ dín in kù, torí wọ́n ti ń dẹwọ́.* Ìyẹn ni wọ́n ṣe ń pariwo pé, ‘A fẹ́ máa lọ, a fẹ́ lọ rúbọ sí Ọlọ́run wa!’
-