-
Nọ́ńbà 9:22Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
22 Ì báà jẹ́ ọjọ́ méjì, oṣù kan tàbí jù bẹ́ẹ̀ lọ ni ìkùukùu náà fi wà lórí àgọ́ ìjọsìn, àwọn ọmọ Ísírẹ́lì ò ní tú àgọ́ wọn ká, wọn ò sì ní gbéra. Àmọ́ tó bá ti gbéra, àwọn náà á gbéra.
-