Ẹ́kísódù 5:21 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 21 Ni wọ́n bá sọ fún Mósè àti Áárónì pé: “Kí Jèhófà bojú wò yín kó sì ṣèdájọ́, torí ẹ ti mú kí Fáráò àti àwọn ìránṣẹ́ rẹ̀ kórìíra wa,* ẹ sì ti fi idà lé wọn lọ́wọ́ kí wọ́n lè pa wá.”+
21 Ni wọ́n bá sọ fún Mósè àti Áárónì pé: “Kí Jèhófà bojú wò yín kó sì ṣèdájọ́, torí ẹ ti mú kí Fáráò àti àwọn ìránṣẹ́ rẹ̀ kórìíra wa,* ẹ sì ti fi idà lé wọn lọ́wọ́ kí wọ́n lè pa wá.”+