Jẹ́nẹ́sísì 46:11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 Àwọn ọmọ Léfì+ ni Gẹ́ṣónì, Kóhátì àti Mérárì.+ Nọ́ńbà 26:57 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 57 Èyí ni àwọn tí wọ́n forúkọ wọn sílẹ̀ nínú àwọn ọmọ Léfì+ ní ìdílé-ìdílé: látọ̀dọ̀ Gẹ́ṣónì, ìdílé àwọn ọmọ Gẹ́ṣónì; látọ̀dọ̀ Kóhátì,+ ìdílé àwọn ọmọ Kóhátì; látọ̀dọ̀ Mérárì, ìdílé àwọn ọmọ Mérárì.
57 Èyí ni àwọn tí wọ́n forúkọ wọn sílẹ̀ nínú àwọn ọmọ Léfì+ ní ìdílé-ìdílé: látọ̀dọ̀ Gẹ́ṣónì, ìdílé àwọn ọmọ Gẹ́ṣónì; látọ̀dọ̀ Kóhátì,+ ìdílé àwọn ọmọ Kóhátì; látọ̀dọ̀ Mérárì, ìdílé àwọn ọmọ Mérárì.