-
Léfítíkù 10:4Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
4 Mósè bá pe Míṣáẹ́lì àti Élísáfánì, àwọn ọmọ Úsíélì,+ arákùnrin bàbá Áárónì, ó sì sọ fún wọn pé: “Ẹ wá gbé àwọn arákùnrin yín kúrò níwájú ibi mímọ́ lọ síbì kan lẹ́yìn ibùdó.”
-
-
Nọ́ńbà 3:30Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
30 Élísáfánì ọmọ Úsíélì+ ni ìjòyè agbo ilé ní ìdílé àwọn ọmọ Kóhátì.
-