ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Ẹ́kísódù 7:2
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 2 Gbogbo ohun tí mo bá pa láṣẹ fún ọ ni kí o sọ, Áárónì ẹ̀gbọ́n rẹ ló máa bá Fáráò sọ̀rọ̀, á sì jẹ́ kí àwọn ọmọ Ísírẹ́lì kúrò ní ilẹ̀ rẹ̀.

  • Ẹ́kísódù 7:4
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 4 Àmọ́ Fáráò ò ní fetí sí yín. Ọwọ́ mi yóò tẹ Íjíbítì, màá sì fi ìdájọ́ tó rinlẹ̀ mú ogunlọ́gọ̀ mi,* ìyẹn àwọn èèyàn mi, àwọn ọmọ Ísírẹ́lì jáde ní ilẹ̀ náà.+

  • Ẹ́kísódù 12:41
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 41 Ní ọjọ́ yìí tí ọgọ́rùn-ún mẹ́rin ó lé ọgbọ̀n (430) ọdún pé ni gbogbo èèyàn Jèhófà tí wọ́n pọ̀ rẹpẹtẹ* kúrò ní ilẹ̀ Íjíbítì.

  • Ìṣe 7:35
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 35 Mósè yìí kan náà, tí wọ́n sọ pé àwọn ò mọ̀ rí, tí wọ́n sọ fún pé: ‘Ta ló fi ọ́ ṣe alákòóso àti onídàájọ́?’+ òun kan náà ni Ọlọ́run rán+ láti jẹ́ alákòóso àti olùdáǹdè nípasẹ̀ áńgẹ́lì tó fara hàn án látinú igi ẹlẹ́gùn-ún.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́