-
Diutarónómì 34:7Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
7 Ẹni ọgọ́fà (120) ọdún ni Mósè nígbà tó kú.+ Ojú rẹ̀ ò di bàìbàì, agbára rẹ̀ ò sì dín kù.