-
Ẹ́kísódù 4:2, 3Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
2 Jèhófà bi í pé: “Kí ló wà lọ́wọ́ rẹ yẹn?” Ó fèsì pé: “Ọ̀pá ni.” 3 Ọlọ́run sọ pé: “Jù ú sílẹ̀.” Ó jù ú sílẹ̀, ló bá di ejò;+ Mósè sì sá fún un.
-