ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Ẹ́kísódù 9:22
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 22 Jèhófà wá sọ fún Mósè pé: “Na ọwọ́ rẹ sí ọ̀run, kí yìnyín lè rọ̀ sórí gbogbo ilẹ̀ Íjíbítì,+ sórí èèyàn àti ẹranko àti gbogbo ewéko ní ilẹ̀ Íjíbítì.”+

  • Ẹ́kísódù 10:12
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 12 Jèhófà wá sọ fún Mósè pé: “Na ọwọ́ rẹ sórí ilẹ̀ Íjíbítì kí àwọn eéṣú lè jáde, kí wọ́n bo ilẹ̀ Íjíbítì, kí wọ́n sì run gbogbo ewéko ilẹ̀ náà tán, gbogbo ohun tí òjò yìnyín ṣẹ́ kù.”

  • Ẹ́kísódù 14:21
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 21 Ni Mósè bá na ọwọ́ rẹ̀ sórí òkun;+ Jèhófà sì mú kí atẹ́gùn líle fẹ́ wá láti ìlà oòrùn ní gbogbo òru yẹn, ó sì bi òkun náà sẹ́yìn. Ó mú kí ìsàlẹ̀ òkun di ilẹ̀ gbígbẹ,+ omi náà sì pínyà.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́