-
Ẹ́kísódù 8:5Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
5 Lẹ́yìn náà, Jèhófà sọ fún Mósè pé: “Sọ fún Áárónì pé, ‘Na ọ̀pá ọwọ́ rẹ sórí àwọn odò, àwọn ipa odò Náílì àti àwọn irà, kí o sì mú kí àkèré bo ilẹ̀ Íjíbítì.’”
-