Sáàmù 78:45 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 45 Ó rán ọ̀wọ́ eṣinṣin mùjẹ̀mùjẹ̀ láti jẹ wọ́n run+Àti àwọn àkèré láti ba ilẹ̀ wọn jẹ́.+