-
Ẹ́kísódù 8:30, 31Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
30 Mósè wá kúrò lọ́dọ̀ Fáráò, ó sì bẹ Jèhófà.+ 31 Jèhófà ṣe ohun tí Mósè sọ, àwọn eṣinṣin mùjẹ̀mùjẹ̀ náà sì kúrò lọ́dọ̀ Fáráò, àwọn ìránṣẹ́ rẹ̀ àti àwọn èèyàn rẹ̀ láìku ẹyọ kan.
-
-
Ẹ́kísódù 9:33Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
33 Mósè wá kúrò nínú ìlú lọ́dọ̀ Fáráò, ó sì tẹ́wọ́ síwájú Jèhófà, ààrá àti yìnyín náà wá dáwọ́ dúró, òjò tó ń rọ̀ náà sì dáwọ́ dúró.+
-