Ìṣe 7:21 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 21 Àmọ́ nígbà tí wọ́n pa á tì,*+ ọmọbìnrin Fáráò gbé e, ó sì tọ́ ọ dàgbà bí ọmọ òun fúnra rẹ̀.+