-
Ẹ́kísódù 8:8Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
8 Fáráò wá pe Mósè àti Áárónì, ó sì sọ pé: “Ẹ bẹ Jèhófà pé kó mú àwọn àkèré náà kúrò lọ́dọ̀ èmi àti àwọn èèyàn mi,+ torí mo fẹ́ yọ̀ǹda àwọn èèyàn náà kí wọ́n máa lọ kí wọ́n lè rúbọ sí Jèhófà.”
-
-
Ẹ́kísódù 9:28Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
28 Ẹ bẹ Jèhófà pé kí ààrá àti yìnyín látọ̀dọ̀ Ọlọ́run dáwọ́ dúró. Lẹ́yìn náà, màá jẹ́ kí ẹ lọ, mi ò sì ní dá yín dúró mọ́.”
-