ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Ẹ́kísódù 4:22, 23
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 22 Kí o sọ fún Fáráò pé, ‘Ohun tí Jèhófà sọ nìyí: “Ọmọ mi ni Ísírẹ́lì, àkọ́bí mi ni.+ 23 Mò ń sọ fún ọ pé, Jẹ́ kí ọmọ mi máa lọ kó lè sìn mí. Àmọ́ tí o ò bá jẹ́ kó lọ, màá pa ọmọkùnrin rẹ, àkọ́bí rẹ.”’”+

  • Sáàmù 78:51
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 51 Níkẹyìn, ó pa gbogbo àkọ́bí Íjíbítì,+

      Ìbẹ̀rẹ̀ agbára ìbímọ wọn nínú àwọn àgọ́ Hámù.

  • Sáàmù 105:36
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 36 Lẹ́yìn náà, ó pa gbogbo àkọ́bí tó wà ní ilẹ̀ wọn,+

      Ìbẹ̀rẹ̀ agbára ìbímọ wọn.

  • Sáàmù 136:10
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 10 Ó pa àwọn àkọ́bí Íjíbítì,+

      Nítorí ìfẹ́ rẹ̀ tí kì í yẹ̀ wà títí láé.

  • Hébérù 11:28
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 28 Ìgbàgbọ́ mú kó ṣe Ìrékọjá, ó sì wọ́n ẹ̀jẹ̀, kí apanirun má bàa pa àwọn àkọ́bí wọn lára.*+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́