-
Ẹ́kísódù 12:30Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
30 Fáráò dìde ní òru yẹn, òun àti gbogbo ìránṣẹ́ rẹ̀ àti gbogbo àwọn ará Íjíbítì yòókù, igbe ẹkún ńlá sì sọ láàárín àwọn ará Íjíbítì, torí kò sí ilé kankan tí èèyàn ò ti kú.+
-