Nọ́ńbà 33:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Ìgbà yẹn ni àwọn ará Íjíbítì ń sin àwọn àkọ́bí wọn+ tí Jèhófà pa torí Jèhófà ti dá àwọn ọlọ́run+ wọn lẹ́jọ́.
4 Ìgbà yẹn ni àwọn ará Íjíbítì ń sin àwọn àkọ́bí wọn+ tí Jèhófà pa torí Jèhófà ti dá àwọn ọlọ́run+ wọn lẹ́jọ́.