-
Ìṣe 7:27, 28Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
27 Àmọ́ ẹni tó ń fìyà jẹ ọmọnìkejì rẹ̀ tì í dà nù, ó ní: ‘Ta ló fi ọ́ ṣe alákòóso àti onídàájọ́ lé wa lórí? 28 Àbí o tún fẹ́ pa mí bí o ṣe pa ará Íjíbítì yẹn lánàá?’
-