Léfítíkù 23:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 “‘Ọjọ́ kẹẹ̀ẹ́dógún oṣù yìí ni Àjọyọ̀ Búrẹ́dì Aláìwú+ fún Jèhófà. Ọjọ́ méje ni kí ẹ fi jẹ búrẹ́dì aláìwú.+ Lúùkù 22:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 22 Àjọyọ̀ Búrẹ́dì Aláìwú, tí wọ́n ń pè ní Ìrékọjá,+ ti ń sún mọ́lé.+ 1 Kọ́ríńtì 5:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Nítorí náà, ẹ jẹ́ ká ṣe àjọyọ̀,+ kì í ṣe pẹ̀lú ìwúkàrà àtijọ́, bẹ́ẹ̀ ni kì í ṣe pẹ̀lú ìwúkàrà ìwà ìbàjẹ́ àti ìwà burúkú, àmọ́ ká ṣe é pẹ̀lú búrẹ́dì aláìwú ti òótọ́ inú àti ti òtítọ́.
6 “‘Ọjọ́ kẹẹ̀ẹ́dógún oṣù yìí ni Àjọyọ̀ Búrẹ́dì Aláìwú+ fún Jèhófà. Ọjọ́ méje ni kí ẹ fi jẹ búrẹ́dì aláìwú.+
8 Nítorí náà, ẹ jẹ́ ká ṣe àjọyọ̀,+ kì í ṣe pẹ̀lú ìwúkàrà àtijọ́, bẹ́ẹ̀ ni kì í ṣe pẹ̀lú ìwúkàrà ìwà ìbàjẹ́ àti ìwà burúkú, àmọ́ ká ṣe é pẹ̀lú búrẹ́dì aláìwú ti òótọ́ inú àti ti òtítọ́.